Ẹyin ara agbegbe aarin gbungbun Ogun, Ogun Central akoko to lati fibo yin Ọmọluabi Pọnbele,Oluwafẹmi Abiọdun-Oni wọle.

0
Ẹyin ara agbegbe aarin gbungbun Ogun, Ogun Central akoko to lati fibo yin Ọmọluabi Pọnbele,Oluwafẹmi Abiọdun-Oni wọle.

Ẹyin ara agbegbe aarin gbungbun Ogun, Ogun Central akoko to lati fibo yin Ọmọluabi Pọnbele,Oluwafẹmi Abiọdun-Oni wọle.

Bi o ti ku fẹrẹ ki eto ibo waye jakejado orileede yii tawọn oludije si ti n jade lati du awọn ipo kọọkan. Bẹẹ ni ipolongo si ti bẹrẹ yatọ sipo Gomina atawọn aṣofin ipinlẹ.

Ki i ṣe tuntun mọ pe ọkan lara awọn oludije fun aṣofin agba fun ẹkun aarin gbungbun iyẹn Ogun Central ni Onimọ ẹrọ Samuel Oluwafẹmi Abiọdun Oni, labẹ ẹgbẹ oṣelu ADC, ẹni ti Ọlọrun sọ pe akoko ti to fun un lati wa sin eeyan rẹ.

Ohun to daju ni pe latigba ti ajọ eleto idibo iyẹn INEC ti fi ontẹ lu agba oṣelu naa gẹgẹ bi oludije, lawọn araalu naa ti n fi atilẹyin wọn han si, ti wọn si lawọn nigbẹkẹle ninu ẹ lati jẹ aṣoju wọn niluu Abuja.

Ko le ṣe ko ma ribẹ, nitori ẹni ti wọn ba ti pe ni ọmọluabi, ko si ki wọn maa ri awọn iwa alubarika yii lara ẹ.

Awọn to mọ oludije ọmọ ẹgbẹ oṣelu ADC yii sọ pe ki i ṣe akoko to fẹẹ gbegba oṣelu lo ṣẹṣẹ di ọmọluabi, wọn ni ọmọ ba ọla nile, to tun fawọn jẹ ninu ọla ẹ ni.

Ọpọ awọn ipa pataki ti wọn lo ti ko lo ti ni ẹmi sisin awọn eeyan ẹ ṣọkan, ti ko si fọrọ wọn ṣere, aṣiwaju ati adari rere ni wọn pe e.

Awọn agba bọ, wọn nile ni a ti n ko ẹṣọ rode, ohun tawọn eeyan ba sọ nibi to ti jade wa lawọn to wa nita yoo gbagbọ iru ẹni ti onitọhun jẹ.

Idi niyii tawọn eeyan ijọba ibilẹ Ọbafẹmi Owode, ko ṣe fọrọ ọmọ wọn to jade dupo yii ṣere rara, tọba tọba, tijoye tijoye atawọn to so ijọba ibilẹ naa pọ, ni wọn dide atilẹyin fun Abọdun Oni.

Ọmọ ẹni ko le ṣe idi bẹbẹrẹ, ki wọn fi ilẹkẹ wọdi ọmọ mii in, gbogbo ọna ni wọn ṣi n gba lati ma jẹ ko bọ mọ wọn lọwọ lọtẹ yii.

Ni bayii, Oluwafẹmi Abiọdun Oni, ti fi gbogbo awọn eeyan ẹ ni Ogun Central lọkanbalẹ pe didun ni ọsan yoo so ti wọn ba le dibo yan oun wọle gẹgẹ aṣofin wọn niluu Abuja.

Ninu alaye to ṣe ọna marun-un lo ti la kalẹ pe o jẹ pataki foun ni eyi ti yoo mu idagbasoke, ilọsiwaju ati itẹsiwaju ba awọn eeyan oun.

O ni eyi ti wọn fi akoko Ogun Central ṣofo niluu Abuja, to jẹ pe ẹni ẹlẹni lo wa gba iṣẹ wọn ṣe ti to ni agbegbe naa.

Lara awọn eto naa eto aabo to fẹsẹ rinlẹ, idajọ ododo to nii ṣe pẹlu iṣeto jọba rere, idagbasoke ati ọrọ aje ninu eyi ti yoo jẹ mudunmudun ijọba tiwa-n-tiwa.

Akoko ti waa to fawọn eeyan Ogun Central, lati fibo won gbe Ọmọluabi Pọnbele, Oluwafemi Abiọdun-Oni wọle fun ibo aṣofin agbɛ lọdun 2027.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

grandpashabethiltonbetporno izlepornoporno izleGrandpashabet Resmihttps://mail.pbidde.org/grandpashabetporno izlededebettipobettipobetjojobetjojobetcasibom girişporno izlejojobetporno izleporno izleporno HD izlematbetcasibomibizabetnesinecasinograndpashabetjojobetgrandpashabetholiganbetmatbetpusulabetvdcasinojojobetwbahisbetbeyjojobetgrandpashabetesbetmarsbahisgrandpashabetmatbetjojobet girişjojobetgrandpashabetgrandpashabet girişcasibomjojobetpusulabetmarsbahis girişimajbetsuperbetinbetciograndpashabet girişsahabetonwinDeneme Bonusucasino sitelerisekabetmercurecasinobetplaycasinomilyoncasinoroyalbetsalvadorteosbetbahiscasinograndpashabet girişcasibomJojobet Girişporno izlejojobetjojobet girişjojobetporn tvmarsbahisholiganbetjojobetgrandpashabetgrandpashabetholiganbetjojobetbetexperjetbahispusulabetcasibomzirvebetbettiltbahiscomgrandpashabetchild porngrandpashabetchild pornsekabetDeneme Bonusu Veren Siteler 2026Deneme Bonusu Veren Sitelerjojobet girişgrandpashabet girişcasibomgrandpashabetjojobet