Ayẹyẹ ọdun ominira: Ọnarebu Azeez Babatunde pe fun isọdọtun ireti awọn ọmọ orileede yii.

0
Ayẹyẹ ọdun ominira: Ọnarebu Azeez Babatunde pe fun isọdọtun ireti awọn ọmọ orileede yii.

Ayẹyẹ ọdun ominira: Ọnarebu Azeez Babatunde pe fun isọdọtun ireti awọn ọmọ orileede yii.

Ọnarebu Sadiq Azeez Babatunde, oludije fun ọmọ ile igbimọ aṣofin fun ẹkun Ifọ keji, labẹ ẹgbẹ oṣelu ADC, nipinlẹ Ogun, ti pe awọn ọmọ orileede yii lati sọ ireti wọn dọtun lakooko ti ayẹyẹ ọdun ominira n lọ lọwọ.

Ninu atẹjade kan to fi sita fun ti ayẹyẹ ọdun kẹrindinlaadọrin ti orileede wa gba ominira lo ti sọ pẹlu idaniloju pe o n ṣe ọmọ olooku orileede wa bẹẹni, o daju pe atunbọtan rere ṣi n pada bọ.

Oludije Ifọ keji tun ṣalaye ṣiwaju pe loootọ ni o ṣi le dara fun wa lorileede, amọ, a gbọdọ bẹrẹ ipilẹ ẹ lati ile, ileewe, ọja, ọfiisi, abule, agbegbe ati ọdọ awọn adari.

Bẹẹ lo ni a gbọdọ wa niṣọkan,ki a ma gba iyapa laaye, iduroṣinṣin ju iwa ibajẹ lọ, agbara lati ṣiṣẹ ju ọlẹ lọ ati isinlu ju imọtara ẹni lọ.

Lẹẹkan si, o tun bawọn ọmọ orileede ṣayọjọ ọdun ominira pẹlu adura pe inu ayọ ati alaafia ni wọn yoo ti ṣe ọdun to n bọ.

Bẹẹ lo tun ran awọn eeyan agbegbe Ifọ keji leti nipa ibo to n bọ, ki wọn fi kaadi idibo wọn gbe oun wọle gẹgẹ bi aṣoju wọn nile igbimọ aṣofin ipinlẹ Ogun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

grandpashabetporno siteleripornoporno izleGrandpashabet Resmihttps://mail.pbidde.org/grandpashabetporno siteleriporno siteleriporno siteleriporno siteleriporno siteleriporno siteleriporno siteleripusulabetporno siteleriDeneme Bonusu Veren SitelerDeneme BonusuDeneme Bonusu Veren SitelerholiganbetBetpuan Girişporno sitelerimarsbahis güncel girişmarsbahismarsbahismarsbahisjojobetholiganbet7711marsbahisporno siteleriDeneme Bonusu Veren Sitelerporno siteleriporno sitelerigrandpashabetcasinolevantgrandpashabetpusulabet güncel girişholiganbetsekabetcasinolevantmatbetmatbet girişpusulabetsekabet girişsekabetholiganbet girişimajbetmatbet girişholiganbetgrandpashabet girişmarsbahispusulabetmatbetpusulabetimajbetjojobetwbahiscasibom girişcasibomcasibomwbahisholiganbetcratosroyalbetcasibomjojobetcasibommarsbahismatbetgrandpashabetimajbetcasibomcasibomcasibomwbahisgrandpashabet güncel girişgrandpashabetgrandpashabetgrandpashabet güncel girişgrandpashabet girişholiganbetjojobetsekabetbetgitgrandpashabet girişgrandpashabetgrandpashabetgrandpashabet güncel girişgrandpashabetgrandpashabetgrandpashabetgiftcardmall/mygiftholiganbetcasibomcasibomgrandpashabet girişcasibom