Awọn Ogun Central ni kin ni Iyabọ Ọbasanjọ wa, lẹyin ọdun mejila to ti sa lọ nidii oṣelu.

0
Awọn Ogun Central ni kin ni Iyabọ Ọbasanjọ wa, lẹyin ọdun mejila to ti sa lọ nidii oṣelu.

Awọn Ogun Central ni kin ni Iyabọ Ọbasanjọ wa, lẹyin ọdun mejila to ti sa lọ nidii oṣelu.

Bo tilẹ jẹ pe ipolongo oṣelu ti bẹrẹ bayii gbogbo nnkan to ti wa laarin araalu ni wọn yoo ma sọ jade nipa awọn oludije to fẹẹ jade lati ṣoju wọn.

Irufẹ ọrọ bẹẹ lawọn kan ni ẹkun Ogun Central fi sọko ọrọ ranṣẹ si Sẹnetọ Iyabọ Ọbasanjọ, oludije fun ipo aṣofin fun ẹkun Ogun Central labẹ ẹgbẹ oṣelu PDP.

Gẹgẹ bi a ṣe mọ, fun igba diẹ sẹyin ni wọn ko gburo obinrin naa mọ lagbo oṣelu iyẹn lẹyin to fipo sẹnetọ to wa silẹ labẹ ẹgbẹ oṣelu PDP.

Fun ọpọ ọdun ni wọn ko gburo ẹ mọ tawọn kan tiẹ sọ pe o ti fi oṣelu silẹ patapata to si lọọ jokoo si oke okun, nibi to ti yan iṣẹ olukọ ni pato to si di Ọjọgbọn.

Gbogbo igba naa lawọn kan sọ pe tipatipa lawọn araalu fi n ri, ti ko si ri tawọn araalu ro mọ.

A fi bo tun ṣe ṣẹyọ pe oun tun fẹẹ gbegba oṣelu tawọn araalu n beere lọwọ rẹ pe ki lo tun wa, kin ni awọn nnkan to gbagbe to tun fẹẹ mu, bi ko ba ṣe ojukokoro.

Ṣebi o ti ṣe daadaa lakooko to wa nibẹ, ṣe o fẹẹ fi ipadabọ ẹ yii ba nnkan jẹ, ki lo de ti ko fawọn ti wọn ko tii debẹ ri ṣoju awọn araalu.

Wọn ni Yoruba sọ pe ẹnikan ki i jẹ ki ilu ko fẹẹ, ko fawọn to tun le ṣe e ju u lọ laye lati di aṣofin agba fun ẹkun Ogun Central..

Bi nnkan ṣe n lọọ yii, o fẹẹ jẹ pe oju awọn araalu ti la, wọn si ti mọ ibi ti wọn n lọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

grandpashabethiltonbetchild porngrandpashabetgrandpashabetGrandpashabet Resmihttps://mail.pbidde.org/grandpashabetporno izlesuperbetin girişsuperbetinganobet giriştipobettipobetcasibomjojobet girişcasibom girişchild pornjojobetporno HD izleporno HD izlechild pornjojobetjojobetjojobet girişholiganbet girişbetpuangrandpashabetholiganbetgrandpashabetbetgitvdcasinopusulabetholiganbetgrandpashabetjojobet girişgrandpashabet girişjojobetjojobet girişgrandpashabetmarsbahismatbetgrandpashabet girişjojobetgrandpashabetholiganbet girişholiganbetgrandpashabet girişsekabetgrandpashabet girişimajbetpusulabetsuperbetinmarsbahis girişsekabet girişpusulabet girişDeneme Bonusu Veren SitelerDeneme Bonusu Veren SitelerBetcio sekabetjojobetcasinoroyalpalacebetteosbetbahiscasino1wingrandpashabetholiganbetgrandpashabetsekabetJojobet Girişchild pornjojobetJojobetgrandpashabet girişgrandpashabetchild pornmarsbahisbettiltbahiscomİbizabetİbizabetnesinecasinobetbeyesbetcashwinmatbetcasibomCasibomMarsbahis GirişvaycasinosonbahisgrandpashabetJojobet Girişmarsbahisgrandpashabetcasibom girişchild porncasibomcasibomMarsbahis Giriş