Ijọ Kerubu ati Serafu ‘Film Ministry’ fẹẹ gbe fiimu meji jade lẹẹkan soso

0
Ijọ Kerubu ati Serafu ‘Film Ministry’ fẹẹ gbe fiimu meji jade lẹẹkan soso

Ijọ Kerubu ati Serafu ‘Film Ministry’ fẹẹ gbe fiimu meji jade lẹẹkan soso

Gbogbo eto lo ti to fun igbejade fiimu onigbagbọ meje ti akọle ẹ jẹ Olori pupọ ati igbeyawo okunkun.

Gẹgẹ bi atẹjade ti oludasilẹ ẹgbẹ naa, Senior Apostle/Prophet Olugbenga Taiwo Ashiyambi tọpọ mọ si Asaph, gbe jade, o ni laipẹ yii ni yoo jade.

O sọ pe fiimu mejeeji jẹ ti onigbagbọ to nii ṣe pẹlu iriri aye to kun fun ọgbọn ati ẹkọ nla.

Asaph ṣalaye pe bo tilẹ jẹ pe ọpọ iṣoro lawọn ba pade lakooko tawọn wa ni lokeṣan ko to di pe Ọlọrun gba gbogbo ogo.

Nigba to n sọ nipa idasilẹ ẹgbẹ naa, oludasilẹ ẹgbẹ naa sọ pe, ” Idasilẹ lati bẹrẹ iṣẹ iranṣẹ yii ti bẹrẹ lati nnkan bi ọdun mejidinlọgbọn ṣẹyin, nigba ti mo rii loju ala mi nigba naa, mo ri Jesu lori igi agbelebu,mo wa n beere pe ọna wo ni mo fẹẹ tọ.

“Loju ẹsẹ mo ri to gbe kamẹra le mi lọwọ pẹlu apoti tawọn oloyinbo pe ni box ati baagi funfun. Bi ẹẹmẹta ọtọọtọ ni mo la iru ala bẹẹ.

“Latigba naa ni emi gan an ti n ṣakiyesi nipa irinajo aye mi, to jẹ pe mo maa ba ara mi laarin awọn oṣere ati pe mo tun rii pe sisọ itan wa gẹgẹ bi ọmọ ẹgbẹ Kerubu ati Serafu, awọn nnkan taa lo lo niyi lati sọ fun gbogbo agbaye nipa ijọ wa.

“Bẹẹ ni mo rii pe kii ṣe gbogbo wa lo ni oore ọfẹ lati da ṣọọṣi silẹ, irufẹ eeyan bẹẹ ni ni, ọna ti Ọlọrun fun mi ni oore ọfẹ lati polongo ihinrere rẹ ni mo tẹle.

“Awọn iriri ti mo ti ri fihan pe ibi ti ẹmi mimọ dari mi si niyẹn atawọn ala ti mo tun la tun jẹri si, koda awọn agba ẹmi ti mo ba pade ohun ti wọn ma sọ ni pe ki n lọ da iṣẹ iranṣẹ gbigbe fiimu nilana kristẹẹni jade.

“Ohun to ṣe pataki fun idasilẹ gbigbe fiimu jade ni lati polongo ihinrere ati pe a ko le jokoo kawọn kan ma sọ isọkusọ tabi gbe itan buruku jade nipa ijọ Kerubu ati Serafu jade, iṣẹ ti wa ni lati tan imọlẹ sawọn ibi to ṣokunkun.

Asaph tun sọ pe, “Mo tun fẹẹ kawọn eeyan tun mọ pe awọn ọmọ ẹgbẹ wa le ni ọgọrun un lati inu ijọ Kerubu ati Serafu, Sacread wa laarin wa, Eternal naa wa, bẹẹ ni Ayọ ni o atawọn ẹka ijọ mi, ohun ti mo n sọ pe inu isọkan ni gbogbo wa wa ko si iyapa”.

“Bẹẹ lo ṣe jẹ pe kaakiri ibi gbogbo lorileede yii lawọn ọmọ ẹgbẹ wa wa taa si jọ jumọ pọ polongo iṣẹ iranṣẹ yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

grandpashabetporno izlepornoporno izleGrandpashabet Resmihttps://mail.pbidde.org/grandpashabetporno siteleriporno siteleriporno siteleriporno siteleriporno siteleriporno izleporno siteleriporno siteleriDeneme Bonusu Veren Sitelerporno siteleribahisfairbahisfair güncel girişcasibommatbetmrkingbahisfair girişporno siteleriDeneme Bonusu Veren Sitelerporno siteleriporno sitelericasibomcasibom güncel girişcasibomgrandpashabetjojobetcasibomholiganbetmatbetcasibom girişgrandpashabetholiganbet girişjojobet girişvdcasino güncel girişjojobet girişmatbet girişcasibomcasibom girişMatbetsekabetmatbetsekabetpusulabetimajbetpusulabetmatbetsekabetsekabetcasibomcasibomvdcasinopusulabetimajbetpusulabetmatbetgrandpashabetcasinoroyalnesinecasinojojobetjojobetjojobetpusulabetgrandpashabetcasibom girişgrandpashabetcasinolevant girişcasibom girişcasinolevantcasinolevantcasibomtipobetcasibomgrandpashabetcasibomgarndpashabetcasibomcasibomcasibomgiftcardmall/mygiftvdcasinojojobetjojobetcasinolevantcasibom güncel girişbetorderimajbetimajbetcasibommrking güncelmrking güncelGrandpashabetcanlı casino siteleriDeneme Bonusu Veren Sitelersahabetdeneme bonusu veren sitelermarsbahisjojobetcasino sitelericanlı casino sitelerideneme bonusumatbetjojobetjojobetgrandpashabet girişjojobet girişgiftcardmall balancegiftcardmallsheratonkingSlotraSahabet Giriş