Pataki lọdun Iṣẹṣe niluu Iroko-Oniroko tilu Iroko

0
Pataki lọdun Iṣẹṣe niluu Iroko-Oniroko tilu Iroko

Pataki lọdun Iṣẹṣe niluu Iroko-Oniroko tilu Iroko

Ki i ṣe tuntun mọ pe ni gbogbo ogunjọ oṣu kẹjọ, nijọba fi silẹ fun ayajọ ọdun iṣẹṣe to wọn si tun fawọn oṣiṣẹ gẹgẹ bi isinmi lẹnu iṣẹ.

Idi niyii tawọn oniṣẹṣe naa ko ṣe fi akoko naa ṣere lati lo lati fi ṣetutu siluu, gbogbo ohun to ba tọ ni wọn si maa n ṣe ki ilu tabi agbegbe ba wa ko le tu sẹ.

Lara awọn ilu nilẹ Yoruba ti ko fọrọ iṣẹṣe ọhun ṣere ni Abule Iroko to ti di ilu bayii, ọdọọdun ni wọn maa n ko ara wọn jọ lati jọ ṣe e.

Ninu ọrọ Ọba Oluṣẹgun Ayinde Feyijinmi, Oniroko tiluu Iroko lo ti sọ pe awọn ti gbaradi fun ti ọdun yii ti yoo waye lọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ to n bọ.

O ni awọn ko fi ọjọ naa ṣere rara nitori ẹ lawọn ṣe maa n gbaradi fun un nitori o nii ṣe pẹlu gbogbo ọmọ ilu atawọn alejo ti wọn fẹ idagbasoke.

O ṣalaye pe, “Gẹgẹ bi ẹ ṣe sọ pe ijọba ti fun wa ni Ogunjọ, oṣu kẹjọ fun ayajọ iṣẹṣe ti wọn si ti fun wa nisinmi, awa naa la beere fun, bi wọn ṣe fawọn onigbagbọ ati musulmi ni isinmi lakooko ọdun wọn.

“Ko ki n ba wa ni alejo mọ, to ba ti n bọ lawa naa ti n murailẹ, bi a ṣe n ṣe niluu Iroko, a maa kọkọ da ifa.

O ni bo tilẹ jẹ pe oun lo maa tọ wọn sọna bi ọdun ọhun yoo ṣe lọ atawọn nnkan tawọn yoo lo.

Kabiyesi ni, ” Ifa lo maa tọ wa sọna nitori a nigbagbọ pe oun ni atọna. Ati pe lọjọ naa, o lawọn nnkankan taa gbọdọ ṣe lọjọ naa.

“Akọkọ nibẹ, a maa n bọ odo Ẹrukomu, bi ẹ ba n bọ lati Eko lọọ si Ogun,bi ẹ ba ti de Toll gate Sango,odo yẹn ni ẹ ma kọja lori ẹ, lati wọnu ilu yẹn.

“Ṣugbọn lọdọ ti wa nibi ti omi naa ti n sun daadaa ni a n pe ni Ẹrukomu, a maa bọ omi yẹn.

“Ni aye atijọ ẹru ki i mu omi yẹn, ibẹ lawọn babanla wa ti maa n pọn omi ti wọn n mu, ti wọn fi ṣe gbogbo nnkan.

“Ni asiko ọdun, awọn baba baba wọn a ti lọ odo yẹn lati yẹ ọna, wọn ti mọ bi wọn ṣe n pe ara wọn, wọn yoo mu ada lati lọọ san awọn oko, a maa lọ bọ omi yẹn fun ara iṣẹṣe ọdun yii.

O ni bawọnba ti kuro nibẹ, o lawọn ibi iṣẹmbaye, tawọn maa kan lọna, igba ẹrọ yoo wa lọwọ wọn, ati igba aje.

Oniroko tun ṣalaye siwaju pe, “Gẹgẹ bi ọba, mo maa wa pẹlu wọn, a jọ maa ṣadura siluu. A maa de oju oori awọn babanla wa lati ṣadura fun wọn bi igbagbọ Yoruba a gbọdọ maa bọ wọn, a pa obi, gbogbo ohun to ba yẹ, a maa ṣe e.

A ma de ọdọ awọn ọmọ ati alejo ilu ti wọn nifẹẹ idagbasoke. Bẹẹ la tun maa de awọn orita to ṣe pataki niluu.

“A maa bọ Ogun ati Eṣu, lẹyin a maa lọ sibi alaalẹ, Orile Iroko la n pe e ibẹ lawọn babanla wa ti ṣẹ. Ibẹ lati maa ṣe gbogbo nnkan ti Ifa ba ni ka ṣe, lẹyin naa lo kan jijẹ mimu.

“Eegun a jade lọjọ naa ati Iguniko, pẹlu ilana ifa, to ba ni ki oro jade, to ba maa fi di alẹ, a o ti polongo fawọn araalu a si gbaṣẹ lọdọ ijọba.

“Loootọ ilu yii kii ṣe abule mọ, o ti dilu gbogbo ẹ la maa yẹwo ti a ko ni fi ara ni ara wa.

Kabiyesi wa ni aarọ kutu ni nnkan bi aago mẹfa idaji ni gbogbo wọn atọba, ijoye, atawọn ọmọọlu yoo ti pade, o nibi tawọn ti n pade.

O ni “Nitori odo la fẹẹ lọ bọ, a ṣi gbọdọ ba oluwẹri nile, bẹẹ bẹẹ la maa ṣe igba ti yoo ba fi di aago mọkanla a ti maa wa ni oju alaalẹ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

grandpashabetJojobetpusulabet girişjojobet girişjojobetporno HD izleimajbetgrandpashabetgrandpashabetporno izleGrandpashabet Resmipusulabet girişkavbetjojobetjojobetjojobetmatadorbetDeneme Bonusu Veren Sitelergrandpashabetpusulabet girişchild pornjojobetholiganbetholiganbetholiganbetholiganbetholiganbetjojobetjojobetjojobetjojobetjojobetjojobetjojobetholiganbetjojobetcasibomgrandpashabetjojobetsuperbetinsuperbetinjojobetjojobetwbahiswbahis girişteosbetbahiscasino1wingrandpashabetgrandpashabet girişmatbetpusulabetimajbetsuperbetinmatbet girişbetciopalacebet girişbetgitradissonbetteosbet girişcratosroyalbet girişpalacebetgrandpashabetradissonbet girişcratosroyalbetgrandpashabetgrandpashabet girişromabet girişbetciopusulabet giriştaraftarium24child porntipobetvdcasino girişjojobetgrandpashabetgrandpashabetgrandpashabetjojobetholiganbetromabetteosbetbaymavi girişbaymavicasibomgrandpashabetbetcio girişdumanbetmatadorbettipobetjojobetcasibommrking5026casibom