Ẹdun ọkan lo maa jẹ fun mi kawọn eeyan ti mo fẹẹ ṣoju fun maa jẹ anfaani mudunmudun ijọba- Ọnarebu Sadiq Azeez Babatunde

0
Ẹdun ọkan lo maa jẹ fun mi kawọn eeyan ti mo fẹẹ ṣoju fun maa jẹ anfaani mudunmudun ijọba- Ọnarebu Sadiq Azeez Babatunde

Ẹdun ọkan lo maa jẹ fun mi kawọn eeyan ti mo fẹẹ ṣoju fun maa jẹ anfaani mudunmudun ijọba- Ọnarebu Sadiq Azeez Babatunde

Oludije fun ipo ọmọ ile igbimọ aṣofin nipinlẹ Ogun, fun ẹkun keji labẹ ẹgbẹ oṣelu ADC, Ọnarebu Sadiq Azeez Babatunde, ti sọ ko si anfaani fun ẹni to n ṣoju awọn ara agbegbe ẹ, ko ma le mu inu wọn dun.

O ni nnkan akọkọ to yẹ ko wa niwaju onitọhun ni ohun ti yoo ti wọn yoo fi maa ṣadura fun, ti wọn yoo si maa ti lẹyin nigba gbogbo.

O sọ pe gẹgẹ bi oludije labẹ ẹgbẹ oṣelu ADC, toun si koju oṣuwọn lati ṣoju awọn eeyan rere ni ẹkun Ifọ keji, gbogbo agbara loun yoo sa lati rii pe idagbasoke deba wọn.

Azeez tun sọ siwaju pe gbogbo awọn aba to le mu ilọsiwaju ba Ifọ keji, ti yoo si mu awọn iṣẹ akanse agbegbe naa loun yoo maa gbe lọ siwaju awọn aṣofin.

O ni,” Bi awọn eeyan mi ni agbegbe Ifọ Keji ba le dibo fun mi gẹgẹ bi aṣofin wọn labẹ ẹgbẹ oṣelu ADC, mo maa rii pe ajọṣepọ to danmọran wa laarin emi atawọn araalu lati le maa mọ bi nnkan ṣe n lọ, mi o si ni jẹ aye alafo ibaṣepọ ṣi ṣilẹ laarin wa”

O fikun ọrọ ẹ pe ipo toun dije fun yii ki i ṣe nipa imọtara ẹni rara bi ko ṣe lati fi sin araalu tọkantọkan ki wọn si le jẹ anfaani mudunmudun ijọba tiwa-n-tiwa.

Babatunde tun ṣalaye lara awọn nnkan to nii lọkan, o sọ pe” Bi mo ṣe woye, ironilagbara ṣe pataki fawọn araalu, nitori bi ọrọ aje wa, nitori eyi mo pinnu lati gbe awọn okoowo diẹdiẹ dide nibi ti wọn yoo ti maa rọwọ mu ṣẹnu paapaa awọn ọlọja, ọdọ atawọn oniṣẹ ọwọ mii, ki i ṣe lati fun wọn ni ẹja, bi ko ṣe bawọn naa yoo ṣe ma pa ẹja”.

O tun ṣọ pe ilera ṣe pataki fawọn agbegbe ti aṣofin ba m ṣoju, oun to si buru ni pe ki alaboyun tabi ọmọde ku iku aitọjọ, idi si ree to fi jẹ pe oun yoo rii pe atunṣe deba awon ile iwosan ti wọn ti n gba itọju ni Ifọ keji paapaa lawọn bii Akute, Alagbado, Alagboole, Ijoko atawọn ibo mii.Ti wọn yoo si tun pese awọn ohun elo to ba yẹ fun wọn.

Babatunde tun sọ pe,” Gbogbo wa la mọ
pe pataki ni ẹkọ jẹ, taa si mọ pe awọn ọmọ wa ni ọjọ ọla wa,erongba mi ni lati mu atunṣe bawọn ileewe alakọọbẹrẹ ati girama ijọba, bẹẹ ni mo tun maa ṣe iranwọ fawọn to ba fẹẹ ṣe idanwo GCE/UTME,eyi yoo mu adinku bawọn ti wọn ko le pari ẹkọ wọn.

O sọ pe idagbasoke ko le ba ilu tawọn ọna ko ba dara tabi dun un wo, idi niyii toun yoo fi ri pe oun gbe awọn abadofin kan dide lati rii pe ijọba ran wọn lọwọ lati ṣatunṣe ki wọn si pese ina sola nitori aabo oju popo.

Oludije ADC tun wa ṣeleri pe bi wọn ba dibo yan oun wọle ninu ibo to n bọ yii, loorekoore ni wọn yoo ma ri oun lati maa fi abọ jẹ wọn nipa bi nnkan ba ṣe n lọ.

O wa sọ pe ikuna ni yoo jẹ foun bawọn to n ṣoju fun ko ba ri ounjẹ jẹ, ti wọn ko rowo ọmọleewe san, ti eto aabo wọn mẹhẹ, ti wọn ko ni ilera to peye, nitori ẹ loun ṣe n lọ gẹgẹ bi agbẹnusọ wọn, toun fẹẹ lọ sin wọn, oun wa bẹbẹ fun ifọwọsowọpọ wọn, ki wọn fi ibo gbe oun wọle.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

grandpashabethiltonbetporno izlepornoporno izleGrandpashabet Resmihttps://mail.pbidde.org/grandpashabetpornojojobetcasibomchild pornjojobet güncel girişonwinonwinchild pornpusulabetossebetbetciowbahiscasibomjojobetgrandpashabetholiganbetpusulabetjojobetpusulabetgrandpashabetbetgitcasibomjojobetcasibomholiganbetmarsbahisjojobet girişgrandpashabetcasibomgrandpashabetgrandpashabetjojobetjojobetjojobetmatbet girişgrandpashabet girişpusulabetpusulabetsekabetmarsbahis güncelmatbet girişsekabet girişDeneme Bonusu Veren Sitelercasino sitelerivdcasinobetexperbahiscasinocasinomilyoncasinoroyalsuperbetinradissonbetbetbeymercurecasinowbahisJojobet Girişporno izlebetciogameofbetchild pornsuperbetin girişcasibombetciobetgitbetgitsuperbetinbetciograndpashabetbetbeymatbetextrabetcratosroyalbetmarsbahisgrandpashabetporno izlecratosroyalbetchild pornDeneme BonusuDDENEME BONUSSU jojobet giriştlcasinoimajbetjojobetsekabetmarsbahisbetciobetciobetciojojobetjojobet girişpalacebetbahsegelsekabetportbetbetgitdedebetbetciojojobet girişMarsbahisMarsbahis Girişroketbetroketbet girişjojobetstarzbet