Erongba mi ni lati jẹ aṣoju rere fawọn ara agbegbe Ewekoro/Ifọ nile igbimọ aṣoju aṣofin

0
Erongba mi ni lati jẹ aṣoju rere fawọn ara agbegbe Ewekoro/Ifọ nile igbimọ aṣoju aṣofin

Erongba mi ni lati jẹ aṣoju rere fawọn ara agbegbe Ewekoro/Ifọ nile igbimọ aṣoju aṣofin

Ọnarebu Ademọla Ọlatunbọsun, oludije fẹgbẹ oṣelu ADC ipinlẹ Ogun fun ipo aṣoju-ṣofin fun ẹkun Ewekoro/Ifọ, niluu Abuja ti sọ erongba oun ni lati jẹ aṣoju rere fawọn to n fẹẹ lọ ṣoju fun ti wọn ba le dibo yan oun wọle ninu ibo ti yoo waye lọdun 2027.

O sọrọ yii lakooko to n ba oniroyin wa fọrọ-jomi-toro-ọrọ, o sọ pe latigba toun ti wa ni kekere ni ifẹ araalu ti wa lọkan oun toun si maa n ro pe kin ni nnkan toun le ṣe lati fi ran ọmọnikeji lọwọ.

Ọlatunbọsun ṣalaye siwaju pe,’ Ko to di pe mo kopa ninu oṣelu ni mo ti fi nnkan ti Ọlọrun fun mi lati dun awọn eeyan mi ninu, ti mo si mọ pe maa tun le ṣe ju bẹẹ lọ, ti wọn da dibo yan mi wọle.

“Ẹgbẹ oṣelu ti APC ti ṣe wọn ti wọn le ṣe lakooko ti wọn ṣoju agbegbe wa iyẹn Ewekoro/Ifọ, ẹ fun emi naa ti mo wa lati ADC lati ṣe ju bẹẹ lọ”

Oludije naa sọ pe oun ko wa lati bu ẹnu atẹ lu awọn to ti ṣoju wọn nile igbimọ aṣoju ṣofin tẹlẹ bi ko ṣe pe ki oun wa ibi ti wọb ku diẹ kaa si lati bẹrẹ iṣẹ nibẹ.

O mẹnuba awọn nnkan to ṣe koko toun yoo ṣiṣẹ le lori toun si mọ pe o ṣe koko toun gbọdọ maa jiroro le loun pẹlu awọn akẹgbẹ oun yooku.

Lara ẹ ni eto ẹkọ, ọgbin, llera, ọrọ aje, imayedẹrun atawọn nnkan mii to ṣe koko ninu igbe aye ọmọ ẹda.

Ọlatunbọsun tun sọ pe, “Bi a ba ni fi ọrọ si abẹ ahọn sọ ni a sọ pe ọna wa dara lawọn agbegbe ti mo fẹẹ ṣoju fun un papa lawọn ọna bii Ewekoro, Ifọ, Akute, Lambẹ, Agbado atawọn ibo mii.

“Igba ojo bayii ti ọna ba n bajẹ tawọn araalu doju kọ iṣoro lawọn ijọba to wa lode yoo ṣiṣẹ awuruju sawọn ọna ọhun, eyi ti ko ni pẹ bajẹ pada.

” Lagbara Ọlọrun bi ẹ ba le dibo yan mi wọle gẹgẹ bi aṣoju ṣofin, gbogbo ọna ni mo maa sa lati ri pe wọn wa ojutu titi lae sawọn ọna ọhun.

“Bakan naa ipese iṣẹ yoo tun wa fawọn ọdọ ti ko ni iṣẹ lọwọ, eyi ti yoo din iṣẹ ati iya ku laarin awọn ọdọ.

“Bẹẹ mo tun pinnu pe awọn ọlọja atawọn oniṣẹ ọwọ ni a ma ro wọn lagbara ti ajọṣepọ to danmọran yoo si loorekoore.”

Ọlatunbọsun wa rọ awọn araalu lati dide atilẹyin nla ki wọn dibo foun gẹgẹ bi aṣoju ṣofin ile igbimọ labẹ ẹgbẹ oṣelu ADC

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

grandpashabetporno izlecasinofastdeneme bonusuGrandpashabet Resmigrandpashabetporno izleporno siteleriporno siteleriDeneme Bonusu Veren Sitelerporno siteleribahisfair girişganobetcasibom girişcasibomcasibom güncelmrwinnerGrandpashabetjoıjobetmarsbahissahabettaraftarium24padişahbetmeritkingsuperbetholiganbetjojobetmarsbahiscasibomjojobetslotbarslotbar girişcanlı maç izletaraftarium24justin tvjustin tvdizipaljustin tvjustin tvmarsbahisiptvjustin tvtaraftarium24justin tvtaraftarium24justin tvmarsbahisiptviptvjustin tvmarsbahisjustin tvporno izlejustin tvjustin tvtaraftarium24dizipaltaraftarium24justin tvpusulabetmarsbahiscasibomcasibomimajbetjojobet girişgrandpashabetimajbetmatbetgrandpashabetvdcasinomatbetimajbetgrandpashabetjojobetgrandpashabetcasibomholiganbetgrandpashabetgrandpashabetgrandpashabetjojobetjojobetjustin tvjojobetjustin tvdeneme bonusutaraftarium24deneme bonusu veren sitelerjustin tvdeneme bonusugrandpashabetgrandpashabetromabetjojobetholiganbet güncel girişholiganbet güncel girişcasibomgrandpashabet girişamkbetbahiscasinodeneme bonusucasino siteleriholiganbetholiganbetgrandpashabetGrandpashabet GirişGrandpashabetgrandpashabetholiganbetjojobetcasibommatbetsekabetgrandpashabetiptv testgrandpashabetjojobetbetticketgiftcardmall/mygiftjojobetmarsbahisgrandpashabetbahis sitelericasino sitelerideneme bonusu veren sitelerbeyaz elma