Orukọ Iyabọ Ọbasanjọ ti ajọ INEC gbe jade gẹgẹ bi oludije sẹnetọ da wahala silẹ

0
Orukọ Iyabọ Ọbasanjọ ti ajọ INEC gbe jade gẹgẹ bi oludije sẹnetọ da wahala silẹ

Orukọ Iyabọ Ọbasanjọ ti ajọ INEC gbe jade gẹgẹ bi oludije sẹnetọ da wahala silẹ

Latigba ti ajọ eleto idibo iyẹn INEC, ti gbe orukọ Sẹnetọ Iyabọ Ọbasanjọ jade gẹgẹ bi oludije fun ipo sẹnetọ fun ẹkun Ogun Central labẹ ẹgbẹ oṣelu PDP, ni oriṣi awuyewuye ti n jade.

Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, ṣe lawọn oloṣelu kan sọ pe Iyalẹnu lo jẹ bi ajọ INEC ṣe le gbe orukọ ẹ jade gẹgẹ bi oludije nitori ọna ti wọn PDP Ogun ṣe faa kalẹ ko bofinmu.

Lakọkọ wọn ni ko kopa ninu ibo abẹle iyẹn pamari ẹgbẹ naa ati pe ẹni ti ko ba kopa, wọn ko le fun un ni tikẹẹti nigba ti ki i ṣe pe wọn fi orukọ ẹ rọpo oludije mii in.

Ati pe bi wọn ba tiẹ fẹẹ fi orukọ ẹ rọpo oludije mii, akoko tajọ INEC maa gbe orukọ bẹẹ jade ko tii to.

Wọn lo dabi ẹni pe o ti n lọwọ ifura ninu pẹlu ajọ eleto idibo, to si yẹ kawọn oloṣelu tete gbe igbesẹ lee lori.

A o ranti pe inu ẹgbẹ oṣelu APC, ni Iyabọ Ọbasanjọ wa tẹlẹ to ti dije fun ipo gomina ṣugbọn ti ko ri tikẹẹti gba ko to binu kọwe fi ẹgbẹ naa silẹ.

Amọ sa, ọkan lara awọn eleto idibo to ba wa sọrọ sọ pe iṣẹ awọn lawọn ṣe, ẹni to ba ni ikunsinu tabi ẹhonu ko pariwo sita tabi lọ sile ẹjọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

grandpashabetporno siteleripornoporno izleGrandpashabet Resmihttps://mail.pbidde.org/grandpashabetporno sitelerimarsbahiscasibomporno izlejojobetporno siteleriporno siteleriporno izlejojobetDeneme Bonusu Veren SitelerGrandpashabetJojobet Girişporno siteleriporno siteleribetsmoveporno siteleriporno siteleriDeneme BonusuGrandpashabet girişjojobetmarsbahisbahsegeldeneme bonusuganobetporno izlejojobetbahsegel3019 marsbahisporno siteleriporno siteleriporno siteleriJojobetporno sitelerimarsbahismarsbahis girişjojobetbetciojojobetgrandpashabetjojobetholiganbetbetciogameofbetgrandpashabet girişcratosroyalbetbetgarantibetgitcasinolevantcasibommatbet güncel girişjojobetteosbetcasibomjojobetpusulabetvdcasinomatbetimajbetcashwincashwinbahiscasinosuperbetinbetbeymercurecasinowbahisgameofbetcratosroyalbetbetgitbahiscasinosuperbetinbetbeymercurecasinowbahisgameofbetbetgaranticratosroyalbettipobetjojobetgrandpashabet girişjojobet girişgrandpashabet girişbetgitcasibomjojobetbetciobahsegelgrandpashabetgrandpashabetjojobetgrandpashabetgrandpashabet